Nọ́ḿbà 7:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

O fún àwọn ọmọ Mérárì ní kẹ̀kẹ́ mẹ́rin àti akọ màlúù mẹ́jọ gẹ́gẹ́ bí iṣẹ́ wọn ṣe jẹ mọ́. Gbogbo wọn wà lábẹ́ àkóso Ítamárì ọmọ Árónì tí í ṣe àlùfáà.

Nọ́ḿbà 7

Nọ́ḿbà 7:2-12