Nọ́ḿbà 7:66 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Áhíésérì ọmọ Ámíṣádáyì, olórí àwọn ọmọ Dánì ni ó mú ọrẹ tirẹ̀ wá ní ọjọ́ kẹwàá.

Nọ́ḿbà 7

Nọ́ḿbà 7:57-67