Nọ́ḿbà 7:43 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọrẹ rẹ̀ ni àwo fàdákà kan, tí ìwọ̀n rẹ̀ jẹ́ àádóje (130) ṣékélì àti àwokòtò kan tí iwọn rẹ̀ jẹ́ àádọ́rin (70) ṣékélì, méjèèjì gẹ́gẹ́ bí iye owó ibi mímọ́, àwo kọ̀ọ̀kan sì kún fún ìyẹ̀fun kíkúnná tí a fi òróró pò bí ẹbọ ohun jíjẹ

Nọ́ḿbà 7

Nọ́ḿbà 7:33-53