Nọ́ḿbà 7:27-30 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

27. Akọ ọ̀dọ́ màlúù kan, àgbò kan àti akọ ọ̀dọ́ àgùntàn ọlọ́dún kan fún ẹbọ sísun;

28. Akọ ewúrẹ́ kan fún ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀;

29. Màlúù méjì, àgbò márùn-ún, òbúkọ márùn ún akọ ọ̀dọ́ àgùntàn ọlọ́dún kan márùn-ún tí wọn o fi rú ẹbọ àlàáfíà. Èyí ni ọrẹ Élíábù ọmọ Hélónì.

30. Élíṣúrì ọmọ Ṣédéúrì olórí àwọn ọmọ Rúbẹ́nì ni ó mú ọrẹ wá ní ọjọ́ kẹrin.

Nọ́ḿbà 7