Nọ́ḿbà 7:23 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Màlúù méjì, àgbò márùn-ún, akọ ewúrẹ́ márùn-un àti akọ ọ̀dọ́ àgùntàn ọlọ́dún kan márùn-un tí wọn ó fi rú ẹbọ àlàáfíà. Èyí ni ọrẹ Nètaníẹ́lì ọmọ Súárì.

Nọ́ḿbà 7

Nọ́ḿbà 7:14-31