Nọ́ḿbà 6:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Irú ẹni bẹ́ẹ̀ gbọdọ̀ yàgò fún wáìnì tàbí ọtí líle, ọtí wáìnì kíkan àti àwọn ohun mímu mìíràn tó bá kan. Kò gbọdọ̀ mu èso àjàrà tàbí kí ó jẹ èṣo àjàrà tútù tàbí gbígbẹ.

Nọ́ḿbà 6

Nọ́ḿbà 6:1-5