Nọ́ḿbà 5:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Pàṣẹ fún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì pé kí wọn ó lé ẹnikẹ́ni tó bá ní ẹ̀tẹ̀, ìtújáde ara ní oríṣìíríṣìí tàbí ẹni tó jẹ́ aláìmọ́ nípa fífọwọ́ kan òkú.

Nọ́ḿbà 5

Nọ́ḿbà 5:1-9