Nọ́ḿbà 4:41 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èyí jẹ́ àpapọ̀ iye àwọn ọmọ Gásónì, àwọn tó ṣiṣẹ́ ní Àgọ́ Ìpàdé. Mósè àti Árónì se bí àṣẹ Olúwa.

Nọ́ḿbà 4

Nọ́ḿbà 4:39-45