Nọ́ḿbà 4:39 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Gbogbo ọmọkùnrin láti ọmọ ọgbọ̀n ọdún títí dé àádọ́ta, gbogbo àwọn tó lè ṣiṣẹ́ ní Àgọ́ Ìpàdé.

Nọ́ḿbà 4

Nọ́ḿbà 4:34-44