Nọ́ḿbà 4:37 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èyí ni àpapọ̀ iye àwọn ọmọ Kóhátì tó ń ṣiṣẹ́ ní Àgọ́ Ìpàdé; tí Mósè àti Árónì kà gẹ́gẹ́ bí Olúwa ti pa á láṣẹ fún Mósè.

Nọ́ḿbà 4

Nọ́ḿbà 4:30-43