Nọ́ḿbà 4:33 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èyí ni iṣẹ́ ìsìn ìdílé àwọn ọmọ Mérárì, bí wọn yóò ti máa ṣiṣẹ́ ní Àgọ́ Ìpàdé lábẹ́ àkóso Ítamárì ọmọ Árónì tí í ṣe àlùfáà.”

Nọ́ḿbà 4

Nọ́ḿbà 4:32-42