Nọ́ḿbà 36:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kò sí ogún kan ní Ísírẹ́lì tí ó gbọdọ̀ kọjá láti ẹ̀yà kan sí ẹ̀yà mìíràn, nítorí gbogbo ọmọ Ísírẹ́lì ni yóò fi ilẹ̀ ogún ẹ̀yà tí wọ́n jogún láti ọ̀dọ̀ babańlá wọn pamọ́.

Nọ́ḿbà 36

Nọ́ḿbà 36:4-8