Nọ́ḿbà 35:33-34 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

33. “ ‘Má ṣe sọ ilẹ̀ tí ẹ wà di àìmọ́. Ìtàjẹ̀ sílẹ̀ sọ ilẹ̀ náà di àìmọ́. Atúnṣe kì yóò sí fún ilẹ̀ tí a ti ta ẹ̀jẹ̀ lé lórí, àyà fi ẹ̀jẹ̀ ẹni tí ó ta á sílẹ̀.

34. Má se sọ di àìmọ́, ilẹ̀ tí ẹ ń gbé, àti èyí tí mo ń gbé, nítorí Èmi JÈHÓFÀ, ń gbé láàrin àwọn ọmọ Ísírẹ́lì.’ ”

Nọ́ḿbà 35