Nọ́ḿbà 35:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Yan àwọn ìlú kan láti jẹ́ gẹ́gẹ́ bí ìlú ìsásí fún yín, kí apani tó pa ènìyàn ní àìmọ̀ máa sá lọ síbẹ̀.

Nọ́ḿbà 35

Nọ́ḿbà 35:5-20