Nọ́ḿbà 35:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Lórí pẹ̀tẹ́lẹ̀ Móábù ní Jọ́dánì tí ó rékọjá láti Jẹ́ríkò, Olúwa sọ fún Mósè pé,

Nọ́ḿbà 35

Nọ́ḿbà 35:1-5