Nọ́ḿbà 33:34-37 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

34. Wọ́n kúrò ní Jótíbátà wọ́n sì pàgọ́ ní Ábírónà.

35. Wọ́n kúrò ní Ábírónà wọ́n sì pàgọ́ ní Esoni-Gébérì.

36. Wọ́n kúrò ní Esoni-Gébérì wọ́n sì pàgọ́ ní Kádésì nínú ihà Ṣínì.

37. Wọ́n kúrò ní Kádésì wọ́n sì pàgọ́ ní orí òkè Hórì, lẹ́bá Édómù.

Nọ́ḿbà 33