Nọ́ḿbà 33:31-34 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

31. Wọ́n kúrò ní Mósérótù wọ́n sì pàgọ́ ní Bene-Jákánì.

32. Wọ́n kúrò ní Bene-Jákánì wọ́n sì pàgọ́ ní Hori-Hágidigádì.

33. Wọ́n kúrò ní Hori-Hágidigádì wọ́n sí pàgọ́ ní Jótíbátà.

34. Wọ́n kúrò ní Jótíbátà wọ́n sì pàgọ́ ní Ábírónà.

Nọ́ḿbà 33