Nọ́ḿbà 33:26-30 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

26. Wọ́n kúrò ní Mákélótì wọ́n sì pàgọ́ ní Táhátì.

27. Wọ́n kúrò ní Táhátì wọ́n sì pàgọ́ ní Térà.

28. Wọ́n kúrò ní Térà wọ́n sì pàgọ́ ní Mítíkà.

29. Wọ́n kúrò ní Mítíkà wọ́n pàgọ́ ní Hásímónà.

30. Wọ́n kúrò ní Hásímónà wọ́n sì pàgọ́ ní Mósérótù.

Nọ́ḿbà 33