Nọ́ḿbà 33:16-21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

16. Wọ́n kúrò ní ihà Ṣínáì wọ́n sì pàgọ́ ní Kabirotu-Hátafà.

17. Wọ́n kúrò ní Kabirotu-Hátafà wọ́n sì pàgọ́ ní Hásérótì.

18. Wọ́n kúrò ní Hásérótì wọ́n sì pàgọ́ ní Rítímà.

19. Wọ́n kúrò ní Rítímà wọ́n sì pàgọ́ ní Rímónì-Pérésì.

20. Wọ́n kúrò ní Rímóni Pérésì wọ́n sì pàgọ́ ní Líbínà.

21. Wọ́n kúrò ní Líbínà wọ́n sì pàgọ́ ní Rísà.

Nọ́ḿbà 33