Nọ́ḿbà 32:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èyí ni nǹkan tí baba yín ṣe nígbà tí mo rán wọn láti Kadesi-Báníyà láti lọ wo ilẹ̀ náà.

Nọ́ḿbà 32

Nọ́ḿbà 32:1-18