Nọ́ḿbà 32:40 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mósè sì fi àwọn ọmọ Gílíádì fún àwọn ọmọ Mákírì àwọn ìrán Mánásè, wọ́n sì tẹ̀dó ṣíbẹ̀.

Nọ́ḿbà 32

Nọ́ḿbà 32:36-42