Nọ́ḿbà 32:29 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó wí fún wọn pé, “Tí àwọn ọmọ Gádì àti ọmọ Rúbẹ́nì, gbogbo ọkùnrin tí ó wọ ìhámọ́ra fún ogun rékọjá odò Jọ́dánì pẹ̀lú níwájú Olúwa, nígbà tí ẹ ṣegun ilẹ̀ náà níwájú yín, Fún wọn ní ilẹ̀ Gílíádì gẹ́gẹ́ bí ìní wọn.

Nọ́ḿbà 32

Nọ́ḿbà 32:20-34