Nọ́ḿbà 32:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí gbogbo yín yóò bá lọ sí Jọ́dánì ní ìhámọ́ra níwájú Olúwa, títí yóò fi lé àwọn ọ̀ta rẹ̀ kúrò níwájú rẹ̀.

Nọ́ḿbà 32

Nọ́ḿbà 32:18-29