Nọ́ḿbà 31:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mósè rán wọn lọ sí ogun, ẹgbẹ̀rún (1000) láti ẹ̀yà kọ̀ọ̀kan pẹ̀lú Fínéhásì ọmọ Élíásárì, ti ó jẹ́ àlùfáà, ti òun ti ohun èlò ibi mímọ́ àti ìpè wọ̀n-ọn-nì ní ọwọ́ rẹ̀.

Nọ́ḿbà 31

Nọ́ḿbà 31:1-12