Nọ́ḿbà 31:32 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èrè tí ó kù lára ìkógun tí àwọn ọmọ ogun kó jẹ́, ọ̀kẹ́ mẹ́rìnlélọ́gbọ̀n (675,000) ó dín ẹgbẹ̀ẹ́dọ́gbọ̀n àgùntàn.

Nọ́ḿbà 31

Nọ́ḿbà 31:22-33