Nọ́ḿbà 31:27 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Pín ohun ìní àti ìkógún náà láàrin àwọn ọmọ ogun náà tí ó kópa nínú ogun náà àti láàrin gbogbo ìjọ.

Nọ́ḿbà 31

Nọ́ḿbà 31:26-31