Nọ́ḿbà 31:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Inú bí Mósè sí àwọn olórí ọmọ ogun, pẹ̀lú àwọn olórí ẹgbẹ̀rún (1000) àti olórí ọrọrún (1000) tí wọ́n ti ogun dé.

Nọ́ḿbà 31

Nọ́ḿbà 31:6-21