Nọ́ḿbà 3:47 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

ìwọ yóò gba sẹ́kẹ́lì márùn ún (5) lórí ẹni kọ̀ọ̀kan gẹ́gẹ́ bí iye owó ibi mímọ́, èyí tí í ṣe ogún gérà.

Nọ́ḿbà 3

Nọ́ḿbà 3:42-51