Nọ́ḿbà 3:43 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àpapọ̀ iye àwọn àkọ́bí ọkùnrin láti ọmọ oṣù kan ó lé, ní àkọsílẹ̀ orúkọ wọn jẹ́ ẹgbàá mọ́kànlá ó lé ọ̀rìnlúgba ó dín méje (22,273).

Nọ́ḿbà 3

Nọ́ḿbà 3:41-51