Nọ́ḿbà 3:25 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Iṣẹ́ àwọn ìdílé Gásónì nínú Àgọ́ Ìpàdé ni pé àwọn yóò máa tọ́jú àgọ́, ìbòrí àgọ́, aṣọ títa ẹnu ọ̀nà àgọ́ ìpàdé,

Nọ́ḿbà 3

Nọ́ḿbà 3:23-27