Nọ́ḿbà 3:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Báyìí èmi fúnra mi ti mú ẹ̀yà Léfì láàrin àwọn ọmọ Ísírẹ́lì dípò gbogbo àkọ́bí ọkùnrin àwọn ọmọbìnrin Ísírẹ́lì. Ti èmi ni àwọn ọmọ Léfì,

Nọ́ḿbà 3

Nọ́ḿbà 3:7-18