Kí ẹ̀yin kí ó rú ẹbọ olóòrùn dídùn sí Olúwa, ẹgbọ̀rọ̀ akọ màlúù kan, àgbò kan, àti akọ ọ̀dọ́ àgùntàn méje ọlọ́dún kan, kí wọn kí ó sì jẹ́ aláìlábùkù fún yín.