Nọ́ḿbà 28:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“ ‘Ní ọjọ́ ìsinmi, pèsè akọ ọ̀dọ́ àgùntàn méjì olọ́dún kan tí kò lábùkù, pẹ̀lú ẹbọ ohun mímu àti ẹbọ ohun jíjẹ tí i ṣe ìdá méjì nínú ìdámẹ́wàá òṣùwọn ìyèfun ìyẹ̀fun tí a fi òróró pò.

Nọ́ḿbà 28

Nọ́ḿbà 28:1-13