Nọ́ḿbà 28:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Yàtọ̀ sí ẹbọ sísun pẹ̀lú ẹbọ ohun mímu, ẹ gbọdọ̀ fi akọ ewúrẹ̀ kọ̀ọ̀kan fún Olúwa gẹ́gẹ́ bí ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀.

Nọ́ḿbà 28

Nọ́ḿbà 28:6-16