Nọ́ḿbà 27:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kín ni ó dé tí orúkọ baba wa yóò parẹ́ nínú ìdílé rẹ̀ nítórí pé kò ní ọmọkùnrin? Fún wa ní ilẹ̀ ìní láàrin àwọn arakùnrin baba wa.”

Nọ́ḿbà 27

Nọ́ḿbà 27:1-14