Nọ́ḿbà 27:22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mósè sì se gẹ́gẹ́ bí Olúwa ti sọ fún un. Ó mú Jóṣúà ó sì mú kí ó dúró níwájú Élíásárì àlùfáà àti níwájú gbogbo ìjọ.

Nọ́ḿbà 27

Nọ́ḿbà 27:14-23