Nọ́ḿbà 27:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà náà ní Olúwa sọ fún Mósè pé, “Mú Jóṣúà ọmọ Núnì, ọkùnrin nínú ẹni tí èmi wà, kí o sì gbé ọwọ́ rẹ lé e.

Nọ́ḿbà 27

Nọ́ḿbà 27:16-23