Nọ́ḿbà 26:38-41 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

38. Àwọn ọmọ Bẹ́ńjámínì gẹ́gẹ́ bí ìdílé wọn nì yí:tí Bẹ́là, ìdílé àwọn ọmọ Bẹ́là;ti Ásíbérì, ìdílé àwọn ọmọ Ásíbérì;ti Áhírámù, ìdílé àwọn ọmọ Áhírámù;

39. ti Ṣúfámù, ìdílé àwọn ọmọ Ṣúfámù;ti Húfámù, ìdílé àwọn ọmọ Húfámù.

40. Àwọn ọmọ Bẹ́là ní pasẹ̀ Árídì àti Náámánì nì yí:ti Árádì, ìdílé àwọn ọmọ Árádì;ti Náámánì, ìdílé àwọn ọmọ Náámánì.

41. Wọ̀nyí ni àwọn ọmọ Bẹ́ńjámínì; gẹ́gẹ́ bí ìdílé wọn; àti àwọn tí a kà nínú wọn jẹ́ ẹgbàáméjìlélógún ó lé ẹgbẹ̀jọ (45,600).

Nọ́ḿbà 26