Nọ́ḿbà 26:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àti àwọn ọmọ Júdà gẹ́gẹ́ bí ìdílé wọn:ti Ṣélà, ìdílé Ṣélà;ti Pérésì, ìdílé Pérésì;ti Sérà, ìdílé Ṣérà.

Nọ́ḿbà 26

Nọ́ḿbà 26:15-27