Nọ́ḿbà 25:17-18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)
17. “Ka àwọn ará Mídíánì sí ọ̀ta, kí o sì pa wọ́n,
18. nítorí pé wọ́n ṣe sí yín gẹ́gẹ́ bí ọ̀ta nígbà tí wọ́n tàn yín nípa ìṣẹ̀lẹ̀ Péórì, àti arábìnrin wọn Kósíbì ọmọbìnrin ìjòyè Mídíánì kan, obìnrin tí a pa nígbà tí àjàkálẹ̀-àrùn ṣẹlẹ̀ nítorí Péórì.