Nọ́ḿbà 25:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà tí àwọn Ísírẹ́lì dúró ní Ṣítímù, àwọn ènìyàn sì bẹ̀rẹ̀ sí í ṣe àgbèrè pẹ̀lú àwọn ọmọbìnrin Móábù,

Nọ́ḿbà 25

Nọ́ḿbà 25:1-5