Nọ́ḿbà 24:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nísinsìnyìí kúrò lọ́dọ̀ mi kíákíá kí o sì máa relé! Mo sọ wí pé màá sọ ọ́ di ẹni ńlá, ṣùgbọ́n Olúwa kò jẹ́ kí o gba èrè yìí.”

Nọ́ḿbà 24

Nọ́ḿbà 24:2-12