Nọ́ḿbà 23:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Láti ṣónṣó ibi gíga orí àpáta ni mo ti rí wọn,láti orí ibi gíga ni mo ti ń wò wọ́n.Mo rí àwọn ènìyàn tí ń gbé lọ́tọ̀wọn kò sì ka ará wọn kún ara àwọn orílẹ̀ èdè.

Nọ́ḿbà 23

Nọ́ḿbà 23:1-12