Nọ́ḿbà 23:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bálákì ṣe bí Bálámù ti sọ, àwọn méjèèjì fi akọ màlúù kọ̀ọ̀kan àti àgbò kọ̀ọ̀kan rúbọ lórí pẹpẹ kọ̀ọ̀kan.

Nọ́ḿbà 23

Nọ́ḿbà 23:1-3