Nọ́ḿbà 23:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bálámù ṣo fún Bálákì pé, “Dúró níbí ní ẹ̀gbẹ́ ẹbọ rẹ nígbà tí mo bá lọ pàdé rẹ̀ níbẹ.”

Nọ́ḿbà 23

Nọ́ḿbà 23:8-25