Nọ́ḿbà 22:34 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bálámù sọ fún ángẹ́lì Olúwa pé, “Mo ti dẹ́ṣẹ̀, èmi kò mọ̀ pé o dúró níwájú ọ̀nà láti dojú kọ mí, Nísinsin yìí tí inú rẹ kò bá dùn, èmi ó padà.”

Nọ́ḿbà 22

Nọ́ḿbà 22:30-37