Nọ́ḿbà 22:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní òwúrọ̀ ọjọ́ kejì Bálámù dìde ó sì sọ fún àwọn ìjòyè Bálákì pé, “Ẹ padà sí orílẹ̀ èdè yín, nítorí tí Olúwa ti kọ̀ láti jẹ́ kí n tẹ̀lé yín.”

Nọ́ḿbà 22

Nọ́ḿbà 22:10-18