Nọ́ḿbà 21:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

wọ́n sì sọ̀rọ̀ lòdì sí Olúwa àti Mósè, wọ́n wí pé, “Èéṣe tí ìwọ fi mú wa jáde láti Éjíbítì kí a ba le wá kú sí ihà yìí? Kò sí oúnjẹ! Kò sì sí omi! Àwa sì kóríra oúnjẹ tí kò dára yìí!”

Nọ́ḿbà 21

Nọ́ḿbà 21:1-7