Nọ́ḿbà 21:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nípa kanga tí àwọn ọmọ aládé gbẹ́,nítorí àwọn ọlọ́lá ènìyàn ni ó gbẹ́ẹ:tí àwọn ọlọ́lá àwọn ènìyàn sì fiọ̀pá aládé àti ọ̀pá oyè wọn gbẹ́.”Nígbà náà wọ́n kúrò láti ihà lọ sí Mátanà,

Nọ́ḿbà 21

Nọ́ḿbà 21:10-25