Nọ́ḿbà 20:28 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mósè bọ́ aṣọ Árónì ó sì gbe wọ ọmọ rẹ̀ Élíásárì, Árónì sì kú sí orí òkè. Nígbà náà Mósè àti Élíásárì sọ̀kalẹ̀ láti orí òkè,

Nọ́ḿbà 20

Nọ́ḿbà 20:27-29